Àwọn Ọmọ Naijiria Sọ Èrò Wọn Nípa Bí Ìjọba Àwarawa Ṣe Sàn Wọ́n Lásìkò Ààrẹ Tinubu



A bá àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ nípa àyájọ́ ijọ̀ba àwarawa lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, June 12, àti bí ìjọba Ààrẹ Bọlá Tinubu ṣe ń mú un ní ọ̀kúnkúndùn tó.

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló fi ẹ̀dùn ọkàn wọn hàn nípa bí ìjọba àwarawa lásìkò Ààrẹ Tinubu nígbà tí àwọn mìíràn ní ìrètí pé ohun gbogbo yóò tó máa lọ ní mẹ̀lọmẹ̀lọ láìpẹ́ jọjọ.

All rights reserved. This material, and other digital content on this website, may not be reproduced, published, broadcast, rewritten or redistributed in whole or in part without prior express written permission from PUNCH.

Contact: [email protected]



Source link

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *