Àwọn Ọmọ Naijiria Sọ Èrò Wọn Nípa Bí Ìjọba Àwarawa Ṣe Sàn Wọ́n Lásìkò Ààrẹ Tinubu
A bá àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ nípa àyájọ́ ijọ̀ba àwarawa lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, June 12, àti bí ìjọba Ààrẹ Bọlá Tinubu ṣe ń mú un ní ọ̀kúnkúndùn tó. Ọ̀pọ̀ èèyàn ló fi ẹ̀dùn ọkàn wọn hàn nípa bí ìjọba àwarawa lásìkò…